Esteri 1:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Ayaba Faṣti náà ṣe àsè fún àwọn obìnrin ní ààfin ọba Ahaswerusi. Viz kapitolaYoruba Bible9 Ayaba Faṣiti pàápàá se àsè fún àwọn obinrin ní ààfin ọba Ahasu-erusi. Viz kapitolaBibeli Mimọ9 Faṣti ayaba sè àse pẹlu fun gbogbo awọn obinrin ni ile ọba ti iṣe ti Ahaswerusi. Viz kapitola |