Online Bible

- Reklamy -




Esteri 1:7 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

7 Kọ́ọ̀bù wúrà onídìí-odó ni a fi ń bu wáìnì fún wọn mu, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì yàtọ̀ sí èkejì, wáìnì ọba pọ̀ púpọ̀, gẹ́gẹ́ bí ọba ṣe lawọ́ sí.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

7 Wọ́n ń fi oríṣìíríṣìí ife wúrà mu ọtí, ọba sì pèsè ọtí lọpọlọpọ gẹ́gẹ́ bí ipò ọlá ńlá rẹ̀.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

7 Ninu ago wura li a si nfun wọn mu, (awọn ohun elo na si yatọ si ara wọn) ati ọti-waini ọba li ọ̀pọlọpọ gẹgẹ bi ọwọ ọba ti to.

Viz kapitola kopírovat




Esteri 1:7

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy