Online Bible

- Reklamy -




Esra 1:7 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

7 Ní àfikún, ọba Kirusi mú àwọn ohun èlò tí ó jẹ́ ti ilé Olúwa jáde wá, tí Nebukadnessari ti kó lọ láti Jerusalẹmu tí ó sì ti kó sí ilé òrìṣà rẹ̀.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

7 Kirusi ọba náà kó àwọn ohun èlò inú ilé OLUWA jáde, tí Nebukadinesari kó wá sinu àwọn ilé oriṣa rẹ̀, láti Jerusalẹmu.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

7 Kirusi ọba si ko ohun èlo ile OLUWA jade, ti Nebukadnessari ti ko jade lọ lati Jerusalemu, ti o si fi sinu ile ọlọrun rẹ̀;

Viz kapitola kopírovat




Esra 1:7

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy