Ẹk. Jer 1:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Jerusalẹmu sì ti dẹ́ṣẹ̀ púpọ̀ ó sì ti di aláìmọ́. Àwọn tí ó ń tẹríba fún un sì kẹ́gàn rẹ̀, nítorí wọ́n ti rí ìhòhò rẹ̀; ó kérora fúnrarẹ̀, ó sì lọ kúrò. Viz kapitolaYoruba Bible8 Jerusalẹmu ti dẹ́ṣẹ̀ burúkú, nítorí náà ó ti di eléèérí. Àwọn tí wọn ń bu ọlá fún un tẹ́lẹ̀ ti ń kẹ́gàn rẹ̀, nítorí pé wọ́n ti rí ìhòòhò rẹ̀. Òun pàápàá ń kérora, ó sì fi ojú pamọ́. Viz kapitolaBibeli Mimọ8 Jerusalemu ti da ẹ̀ṣẹ gidigidi, nitorina li o ṣe di ẹni-irira: gbogbo awọn ti mbu ọla fun u kẹgan rẹ̀, nitoripe nwọn ri ihoho rẹ̀: lõtọ on kẹdùn, o si yi ẹ̀hin pada. Viz kapitola |