Ẹk. Jer 1:22 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 “Jẹ́ kí ìwà ìkà wọn wá síwájú rẹ; jẹ wọ́n ní yà bí o ṣe jẹ mí ní yà nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi. Ìrora mi pọ̀ ọkàn mi sì rẹ̀wẹ̀sì.” Viz kapitolaYoruba Bible22 “Ranti gbogbo ìwà ibi wọn, kí o sì jẹ wọ́n níyà; bí o ti jẹ mí níyà, nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi. Ìrora mi pọ̀ ọkàn mi sì rẹ̀wẹ̀sì.” Viz kapitolaBibeli Mimọ22 Jẹ ki gbogbo ìwa-buburu wọn wá si iwaju rẹ; si ṣe si wọn, gẹgẹ bi iwọ ti ṣe si mi nitori gbogbo irekọja mi: nitori ikẹdùn mi pọ̀, ọkàn mi si rẹ̀wẹsi. Viz kapitola |