Online Bible

- Reklamy -




Ẹk. Jer 1:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

19 “Mo pe àwọn ọ̀rẹ́ mi ṣùgbọ́n wọ́n dà mí. Àwọn olórí àlùfáà àti àgbàgbà mi ṣègbé sínú ìlú nígbà tí wọ́n ń wá oúnjẹ tí yóò mú wọn wà láààyè.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

19 “Mo ké pe àwọn alajọṣepọ mi, ṣugbọn títàn ni wọ́n tàn mí; àwọn alufaa ati àwọn àgbààgbà mi ṣègbé láàrin ìlú, níbi tí wọn ti ń wá oúnjẹ kiri, tí wọn óo jẹ, kí wọn lè lágbára

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

19 Emi pè awọn olufẹ mi, awọn wọnyi tàn mi jẹ: awọn alufa mi, ati àgbagba mi jọwọ ẹmi wọn lọwọ ni ilu, nigbati nwọn nwá onjẹ wọn lati mu ẹmi wọn sọji.

Viz kapitola kopírovat




Ẹk. Jer 1:19

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy