Online Bible

- Reklamy -




Ẹk. Jer 1:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 Sioni na ọwọ́ jáde, ṣùgbọ́n kò sí olùtùnú fún un. Olúwa ti pàṣẹ fún Jakọbu pé àwọn ará ilé rẹ̀ di ọ̀tá fún un Jerusalẹmu ti di ohun aláìmọ́ láàrín wọn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

17 “Sioni na ọwọ́ rẹ̀ fún ìrànwọ́, Ṣugbọn kò sí ẹni tí ó ràn án lọ́wọ́, OLUWA ti pàṣẹ pé, kí àwọn aládùúgbò Jakọbu di ọ̀tá rẹ̀; Jerusalẹmu sì ti di eléèérí láàrin wọn.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

17 Sioni nà ọwọ rẹ̀ jade, kò si sí ẹnikan lati tù u ninu: Oluwa ti paṣẹ niti Jakobu pe, ki awọn aninilara rẹ̀ ki o yi i kakiri: Jerusalemu dabi obinrin ẹlẹgbin lãrin wọn.

Viz kapitola kopírovat




Ẹk. Jer 1:17

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy