Online Bible

- Reklamy -




Ẹk. Jer 1:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 “Ìdí nìyí tí mo fi ń sọkún tí omijé sì ń dà lójú mi, Olùtùnú àti ẹni tí ó le mú ọkàn mi sọjí jìnnà sí mi, kò sí ẹni tí yóò dá ẹ̀mí mi padà. Àwọn ọmọ mi di aláìní nítorí ọ̀tá ti borí.”

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

16 “Nítorí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọnyi ni mo ṣe sọkún; tí omijé ń dà lójú mi; olùtùnú jìnnà sí mi, kò sí ẹni tí ó lè dá mi lọ́kàn le. Àwọn ọmọ mi ti di aláìní, nítorí pé àwọn ọ̀tá ti borí wa.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

16 Emi nsọkun nitori nkan wọnyi; oju mi! oju mi ṣàn omi silẹ, nitoripe olutunu ati ẹniti iba mu ọkàn mi sọji jina si mi: awọn ọmọ mi run, nitoripe ọta bori.

Viz kapitola kopírovat




Ẹk. Jer 1:16

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy