Online Bible

- Reklamy -




Ẹk. Jer 1:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 “Ó rán iná láti òkè sọ̀kalẹ̀ sínú egungun ara mi. Ó dẹ àwọ̀n fún ẹsẹ̀ mi, ó sì yí mi padà. Ó ti pa mí lára mó ń kú lọ ní gbogbo ọjọ́.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

13 “Ó rán iná láti òkè ọ̀run wá; ó dá a sí egungun mi; ó dẹ àwọ̀n sílẹ̀ fún mi; ó sì dá mi pada. Mo dàbí odi, mo sì fi ìgbà gbogbo dákú.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

13 Lati oke li a ti rán iná sinu egungun mi, o si ràn ninu rẹ̀: On ti nà àwọn fun ẹsẹ mi, o ti yi mi pada sẹhin; O ti mu mi dahoro, mo si rẹ̀wẹsi lojojumọ.

Viz kapitola kopírovat




Ẹk. Jer 1:13

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy