Online Bible

- Reklamy -




Ẹk. Jer 1:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Ọ̀tá ti gbọ́wọ́ lé gbogbo ìní rẹ; o rí pé àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wọ ibi mímọ́ rẹ— àwọn tí o ti kọ̀sílẹ̀ láti wọ ìpéjọpọ̀ rẹ.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

10 Ọ̀tá ti tọwọ́ bọ ilé ìṣúra rẹ̀, wọ́n sì ti kó gbogbo nǹkan iyebíye inú rẹ̀ lọ; ó ń wo àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, tí wọn ń wọ ibi mímọ́ rẹ̀. Àwọn tí ó pàṣẹ pé wọn kò gbọdọ̀ dé àwùjọ àwọn eniyan rẹ̀.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

10 Aninilara ti nà ọwọ rẹ̀ jade sori gbogbo ohun daradara rẹ̀: nitori on ti ri pe awọn orilẹ-ède wọ ibi-mimọ́ rẹ̀, eyiti iwọ paṣẹ pe, nwọn kì o wọ inu ijọ tirẹ.

Viz kapitola kopírovat




Ẹk. Jer 1:10

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy