Eksodu 1:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Wàyí o, Josẹfu àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú, Viz kapitolaYoruba Bible6 Nígbà tí ó yá, Josẹfu kú, gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ náà kú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan títí tí gbogbo ìran náà fi kú tán. Viz kapitolaBibeli Mimọ6 Josefu si kú, ati gbogbo awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo iran na. Viz kapitola |