Efesu 1:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Èmi kò sì sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, àti láti máa rántí yín nínú àdúrà mi; Viz kapitolaYoruba Bible16 kò sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, mo sì ń ranti yín ninu adura mi. Viz kapitolaBibeli Mimọ16 Emi kò si simi lati mã dupẹ nitori nyin, ati lati mã darukọ nyin ninu adura mi; Viz kapitola |