Online Bible

- Reklamy -




Deuteronomi 1:3 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Ní ìgbà tí ó pé ogójì ọdún, ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kọ́kànlá, Mose sọ ohun gbogbo tí Ọlọ́run pàṣẹ nípa àwọn ọmọ Israẹli fún wọn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

3 Ní ọjọ́ kinni oṣù kọkanla, ní ogoji ọdún tí wọ́n ti kúrò ní Ijipti, ni Mose bá àwọn eniyan Israẹli sọ ohun tí OLUWA pàṣẹ fún un láti sọ fún wọn;

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

3 O si ṣe nigbati o di ogoji ọdún, li oṣù kọkanla, li ọjọ́ kini oṣù na, ni Mose sọ fun awọn ọmọ Israeli, gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA ti fun u li aṣẹ fun wọn;

Viz kapitola kopírovat




Deuteronomi 1:3

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy