Online Bible

- Reklamy -




A. Oni 1:35 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

35 Àwọn ará Amori ti pinnu láti dúró lórí òkè Heresi àti òkè Aijaloni àti ti Ṣaalbimu, ṣùgbọ́n nígbà tí ẹ̀yà Josẹfu di alágbára wọ́n borí Amori wọ́n sì mú wọn sìn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

35 Àwọn ará Amori kọ̀, wọn kò jáde ní òkè Heresi, Aijaloni ati Ṣaalibimu, ṣugbọn àwọn ọmọ Josẹfu kò fi wọ́n lọ́rùn sílẹ̀ títí tí àwọn ọmọ Josẹfu fi bẹ̀rẹ̀ sí fi tipátipá kó wọn ṣiṣẹ́.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

35 Awọn Amori si ngbé òke Heresi, ni Aijaloni, ati ni Ṣaalbimu: ọwọ́ awọn ara ile Josefu bori, nwọn si di ẹniti nsìn.

Viz kapitola kopírovat




A. Oni 1:35

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy