Online Bible

- Reklamy -




2 Timotiu 1:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Nítorí náà, má ṣe tijú láti jẹ́rìí nípa Olúwa wa, tàbí èmi òǹdè rẹ̀; ṣùgbọ́n kí ìwọ ṣe alábápín nínú ìpọ́njú ìhìnrere nípa agbára Ọlọ́run,

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

8 Nítorí náà má ṣe tijú láti jẹ́rìí fún Oluwa wa tabi fún èmi tí mo wà lẹ́wọ̀n nítorí rẹ̀. Ṣugbọn gba ìjìyà tìrẹ ninu iṣẹ́ ìyìn rere pẹlu agbára Ọlọrun,

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

8 Nitorina máṣe tiju ẹrí Oluwa wa, tabi emi ondè rẹ̀: ṣugbọn ki iwọ ki o ṣe alabapin ninu ipọnju ihinrere gẹgẹ bi agbara Ọlọrun;

Viz kapitola kopírovat




2 Timotiu 1:8

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy