Online Bible

- Reklamy -




1 Timotiu 1:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 Ète àṣẹ náà ni ìfẹ́ ti ń jáde wá láti inú ọkàn mímọ́ àti ẹ̀rí ọkàn rere àti ìgbàgbọ́ àìṣẹ̀tàn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

5 Ìdí tí mo fi pa àṣẹ yìí ni láti ta ìfẹ́ àtọkànwá jí ninu rẹ, pẹlu ẹ̀rí ọkàn rere ati igbagbọ tí kò lẹ́tàn.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

5 Ṣugbọn opin aṣẹ na ni ifẹ lati ọkàn mimọ́ ati ẹri-ọkan rere ati igbagbọ́ aiṣẹtan wa.

Viz kapitola kopírovat




1 Timotiu 1:5

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy