Online Bible

- Reklamy -




Romu 1:6 - Bibeli Mimọ

6 Larin awọn ẹniti ẹnyin pẹlu ti a pè lati jẹ ti Jesu Kristi:

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

6 Ẹ̀yin tí mò ń kọ ìwé yìí sí náà wà lára àwọn tí Jesu Kristi pè.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Ẹ̀yin pẹ̀lú si wa lára àwọn tí a pè sọ́dọ̀ Jesu Kristi.

Viz kapitola kopírovat




Romu 1:6

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy