Oniwaasu 1:2 - Bibeli Mimọ2 Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Viz kapitolaYoruba Bible2 Asán ninu asán, bí ọ̀jọ̀gbọ́n ti wí, asán ninu asán, gbogbo rẹ̀ asán ni. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 “Asán inú asán!” oníwàásù náà wí pé, “Asán inú asán! Gbogbo rẹ̀ asán ni.” Viz kapitola |