Ọbadiah 1:9 - Bibeli Mimọ9 Awọn alagbara rẹ yio si bẹ̀ru, iwọ Temani, nitori ki a le ke olukuluku ti ori oke Esau kuro nitori ipania. Viz kapitolaYoruba Bible9 Ìwọ ìlú Temani, ìbẹ̀rùbojo yóo dé bá àwọn akọni rẹ, gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní òkè Esau ni a óo sì fi idà pa. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, Ìwọ Temani, gbogbo àwọn tó wà ní orí òkè Esau ní a ó gé kúrò nínú ìpànìyàn náà. Viz kapitola |