Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:6 - Bibeli Mimọ

6 Bawo li a ti ṣawari awọn nkan Esau! bawo li a ti wá awọn ohun ikọkọ rẹ̀ jade!

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

6 Ogun ti kó Esau, gbogbo ìṣúra rẹ̀ ni wọ́n ti kó tán!

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Báwo ni a ṣe ṣe àwárí nǹkan Esau, tí a sì wá ohun ìní ìkọ̀kọ̀ rẹ̀ jáde.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:6

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy