Ọbadiah 1:5 - Bibeli Mimọ5 Bi awọn olè tọ̀ ọ wá, bi awọn ọlọṣà li oru, (bawo li a ti ke ọ kuro!) nwọn kì yio ha jale titi nwọn fi ni to? bi awọn aka-eso-ajara wá sọdọ rẹ, nwọn kì yio ha fi ẽṣẹ́ diẹ silẹ? Viz kapitolaYoruba Bible5 “Bí àwọn olè bá wá bá ọ lóru, tí àwọn ọlọ́ṣà bá wá ká ọ mọ́lé lọ́gànjọ́, ṣé wọn kò ní hàn ọ́ léèmọ̀? Ṣebí ohun tí wọ́n bá fẹ́ ninu ẹrù rẹ ni wọn óo kó? Bí àwọn tí wọn ń kórè àjàrà bá wá sọ́dọ̀ rẹ, ṣebí wọn a máa fi díẹ̀ sílẹ̀? Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 “Bí àwọn olè tọ̀ ọ́ wá, bí àwọn ọlọ́ṣà ní òru, Háà! Irú ìparun wo ló dúró dè ọ́: wọn kò ha jalè tó bí wọ́n ti fẹ́? Bí àwọn tí ń ká èso àjàrà tọ̀ ọ́ wá, wọn kò ha ni fi èso àjàrà díẹ̀ sílẹ̀? Viz kapitola |