Ọbadiah 1:21 - Bibeli Mimọ21 Awọn olugbala yio si goke Sioni wá lati ṣe idajọ oke Esau; ijọba na yio si jẹ ti Oluwa. Viz kapitolaYoruba Bible21 Àwọn olùgbàlà yóo lọ láti Sioni, wọn yóo jọba lórí òkè Edomu; ìjọba náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.” Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Àwọn tó ń gba ni là yóò sì gòkè Sioni wá láti jẹ ọba lé orí àwọn òkè Esau. Ìjọba náà yóò sì jẹ́ ti Olúwa. Viz kapitola |