Ọbadiah 1:20 - Bibeli Mimọ20 Ati igbèkun ogun yi, ti awọn ọmọ Israeli ti o wà larin awọn ara Kenaani, titi de Sarefati; ati igbèkun Jerusalemu ti o wà ni Sefaradi, yio ni awọn ilu nla gusu. Viz kapitolaYoruba Bible20 Àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Hala wọ́n óo gba ilẹ̀ Fonike títí dé Sarefati; àwọn eniyan Jerusalẹmu tí wọ́n wà ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Sefaradi yóo gba àwọn ìlú tí ó wà ní Nẹgẹbu. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní20 Àwọn ìgbèkùn Israẹli tí ó wà ní Kenaani yóò ni ilẹ̀ títí dé Sarefati; àwọn ìgbèkùn láti Jerusalẹmu tí ó wà ní Sefaredi yóò ni àwọn ìlú gúúsù ní ìní Viz kapitola |