Ọbadiah 1:2 - Bibeli Mimọ2 Kiyesi i, mo ti sọ iwọ di kekere larin awọn keferi: iwọ di gigàn lọpọlọpọ. Viz kapitolaYoruba Bible2 Ó sọ fún Edomu pé, “Wò ó, n óo sọ ọ́ di yẹpẹrẹ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù; gbogbo ayé pátá ni yóo máa fi ọ́ ṣẹ̀sín. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 “Kíyèsi i, Èmi yóò sọ ọ́ di kékeré láàrín àwọn kèfèrí; ìwọ yóò sì di gígàn lọ́pọ̀lọpọ̀, Viz kapitola |