Ọbadiah 1:19 - Bibeli Mimọ19 Awọn ara gusu yio ni oke Esau; awọn ti pẹ̀tẹlẹ yio si ni awọn ara Filistia: nwọn o si ni oko Efraimu, ati oko Samaria: Benjamini yio si ni Gileadi. Viz kapitolaYoruba Bible19 Àwọn tí wọn ń gbé Nẹgẹbu yóo gba òkè Edomu, àwọn tí wọ́n wà ní ẹsẹ̀ Ṣefela yóo gba ilẹ̀ àwọn ará Filistia; wọn yóo gba gbogbo agbègbè Efuraimu ati ilẹ̀ Samaria, àwọn ará Bẹnjamini yóo sì gba ilẹ̀ Gileadi. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Àwọn ará gúúsù yóò ni òkè Esau, àwọn ará ẹsẹ̀ òkè yóò ni ilẹ̀ àwọn ará Filistini ní ìní. Wọn yóò sì ni oko Efraimu àti Samaria; Benjamini yóò ní Gileadi ní ìní. Viz kapitola |