Ọbadiah 1:14 - Bibeli Mimọ14 Bẹ̃ni iwọ kì ba ti duro ni ikorita lati ké awọn tirẹ̀ ti o ti salà kuro; bẹ̃ni iwọ kì ba ti sé awọn tirẹ̀ ti o kù li ọjọ wahala mọ. Viz kapitolaYoruba Bible14 O kì bá tí dúró sí oríta, kí o máa mú àwọn tí wọn ń gbìyànjú láti sá àsálà; o kì bá tí fà wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní14 Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nà láti ké àwọn tirẹ̀ tó ti sálà kúrò. Ìwọ kì bá tí fa àwọn tó ṣẹ́kù nínú wọn lélẹ̀ ní ọjọ́ wàhálà wọn. Viz kapitola |