Numeri 1:54 - Bibeli Mimọ54 Bayi ni awọn ọmọ Israeli si ṣe; gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA ti paṣẹ fun Mose, bẹ̃ni nwọn ṣe. Viz kapitolaYoruba Bible54 Àwọn ọmọ Israẹli sì ṣe gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún Mose. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní54 Àwọn ọmọ Israẹli sì ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mose. Viz kapitola |