Numeri 1:41 - Bibeli Mimọ41 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Aṣeri, o jẹ́ ọkẹ meji o le ẹdẹgbẹjọ. Viz kapitolaYoruba Bible41 jẹ́ ọ̀kẹ́ meji le ẹẹdẹgbẹjọ (41,500). Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní41 Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Aṣeri jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (41,500). Viz kapitola |