Online Bible

- Reklamy -




Numeri 1:37 - Bibeli Mimọ

37 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Benjamini, o jẹ́ ẹgba mẹtadilogun o le egbeje.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

37 jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogun ó lé egbeje (35,400).

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

37 Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Benjamini jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tà-dínlógún ó-lé-egbèje (35,400).

Viz kapitola kopírovat




Numeri 1:37

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy