Matiu 1:11 - Bibeli Mimọ11 Josiah si bí Jekoniah ati awọn arakunrin rẹ̀, nigba ikolọ si Babiloni. Viz kapitolaYoruba Bible11 Josaya bí Jekonaya ati àwọn arakunrin rẹ̀ ní àkókò tí wọn kó àwọn ọmọ Israẹli lẹ́rú lọ sí Babiloni. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Josiah sì ni baba Jekoniah àti àwọn arákùnrin rẹ̀ ní àkókò ìkólọ sí Babeli. Viz kapitola |