Online Bible

- Reklamy -




Luku 1:30 - Bibeli Mimọ

30 Angẹli na si wi fun u pe, Má bẹ̀ru, Maria: nitori iwọ ti ri ojurere lọdọ Ọlọrun.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

30 Angẹli náà sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, Maria, nítorí o ti bá ojurere Ọlọrun pàdé.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Ṣùgbọ́n angẹli náà wí fún un pé, “Má bẹ̀rù, Maria: nítorí ìwọ ti rí ojúrere lọ́dọ̀ Ọlọ́run.

Viz kapitola kopírovat




Luku 1:30

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy