Luku 1:16 - Bibeli Mimọ16 On o si pa pipọ da ninu awọn ọmọ Israeli si Oluwa Ọlọrun wọn. Viz kapitolaYoruba Bible16 ọpọlọpọ àwọn ọmọ Israẹli ni yóo sì yipada sí Oluwa Ọlọrun wọn. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Òun ó sì yí ènìyàn púpọ̀ padà nínú àwọn ọmọ Israẹli sí Olúwa Ọlọ́run wọn. Viz kapitola |