Kolose 1:15 - Bibeli Mimọ15 Ẹniti iṣe aworan Ọlọrun ti a kò ri, akọbi gbogbo ẹda: Viz kapitolaYoruba Bible15 Eniyan kò lè rí Ọlọrun, ṣugbọn ọmọ yìí ni àwòrán rẹ̀, òun ni àkọ́bí ohun gbogbo tí a dá. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní15 Kristi ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò le rí, àkọ́bí gbogbo ẹ̀dá. Viz kapitola |