Joẹli 1:6 - Bibeli Mimọ6 Nitori orilẹ-ède kan goke wá si ilẹ mi, o li agbara, kò si ni iye, ehin ẹniti iṣe ehin kiniun, o si ni erìgi abo kiniun. Viz kapitolaYoruba Bible6 Orílẹ̀-èdè kan ti dojú kọ ilẹ̀ mi, wọ́n lágbára, wọ́n pọ̀, wọn kò sì lóǹkà; eyín wọn dàbí ti kinniun. Ọ̀gàn wọn sì dàbí ti abo kinniun. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti ṣígun sí ilẹ̀ mìíràn ó ní agbára púpọ̀, kò sì ní òǹkà; ó ní eyín kìnnìún ó sì ní èrìgì abo kìnnìún. Viz kapitola |