Joẹli 1:12 - Bibeli Mimọ12 Ajara gbẹ, igi ọ̀pọtọ́ si rọgbẹ; igi pomegranate, igi ọ̀pẹ pẹlu, ati igi appili, gbogbo igi igbo li o rọ: nitoriti ayọ̀ rọgbẹ kuro lọdọ awọn ọmọ enia. Viz kapitolaYoruba Bible12 Èso àjàrà ti rọ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì ti ń gbẹ. Igi pomegiranate, igi ọ̀pẹ ati igi ápù, ati gbogbo àwọn igi eléso ti gbẹ, inú ọmọ eniyan kò sì dùn mọ́. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Àjàrà gbẹ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì rọ̀ dànù; igi pomegiranate, igi ọ̀pẹ pẹ̀lú, àti igi apiili, gbogbo igi igbó ni o rọ: Nítorí náà ayọ̀ ọmọ ènìyàn gbẹ kúrò lọ́dọ̀ wọn. Viz kapitola |