Isaiah 1:7 - Bibeli Mimọ7 Ilẹ nyin di ahoro, a fi iná kun ilu nyin: ilẹ nyin, alejo jẹ ẹ run li oju nyin, o si di ahoro, bi eyiti awọn alejo wó palẹ. Viz kapitolaYoruba Bible7 Orílẹ̀-èdè yín ti di ahoro, wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín. Àwọn àjèjì sì ti jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín. Ó di ahoro bí èyí tí àwọn àjèjì wó palẹ̀. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní7 Orílẹ̀-èdè yín dahoro, a dáná sun àwọn ìlú yín, oko yín ni àwọn àjèjì ti jẹ run lójú ara yín náà, ni gbogbo rẹ̀ ṣòfò bí èyí tí àwọn àjèjì borí rẹ̀. Viz kapitola |