Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:28 - Bibeli Mimọ

28 Iparun awọn alarekọja pẹlu awọn ẹlẹṣẹ yio wà pọ̀, ati awọn ti o kọ̀ Oluwa silẹ li a o parun.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

28 Ṣugbọn a óo pa àwọn ọlọ̀tẹ̀ ati àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ run, àwọn tí ó kọ OLUWA sílẹ̀ yóo sì ṣègbé.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

28 Ṣùgbọ́n àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni a ó parun. Àwọn tí ó bá sì kọ Olúwa sílẹ̀ ni yóò ṣègbé.

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:28

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy