Isaiah 1:27 - Bibeli Mimọ27 Idajọ li a o fi rà Sioni pada, ati awọn ti o pada bọ̀ nipa ododo. Viz kapitolaYoruba Bible27 A óo fi ẹ̀tọ́ ra Sioni pada; a óo sì fi òdodo ra àwọn tí ó bá ronupiwada ninu rẹ pada. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní27 A ó fi ìdájọ́ òtítọ́ ra Sioni padà, àti àwọn tí ó ronúpìwàdà pẹ̀lú òdodo. Viz kapitola |