Isaiah 1:21 - Bibeli Mimọ21 Ilu otitọ ha ti ṣe di àgbere! o ti kún fun idajọ ri; ododo ti gbe inu rẹ̀ ri; ṣugbọn nisisiyi, awọn apania. Viz kapitolaYoruba Bible21 Ìlú tí ó ti jẹ́ olódodo rí tí ń ṣe bí aṣẹ́wó, ìlú tí ó ti kún fún ẹ̀tọ́ ati òdodo rí, ti kún fún ìpànìyàn. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Wo bí ìlú òtítọ́ ṣe di àgbèrè! Ó ti kún fún ìdájọ́ òtítọ́ nígbà kan rí, òdodo ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí, ṣùgbọ́n báyìí àwọn apànìyàn! Viz kapitola |