Hosea 1:5 - Bibeli Mimọ5 Yio si ṣe li ọjọ na, li emi o ṣẹ́ ọrun Israeli ni afonifojì Jesreeli. Viz kapitolaYoruba Bible5 Ní ọjọ́ náà, n óo run àwọn ọmọ ogun Israẹli ní àfonífojì Jesireeli.” Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 Ní ọjọ́ náà ni Èmi yóò ṣẹ́ ọrun Israẹli ní Àfonífojì Jesreeli.” Viz kapitola |