Heberu 1:11 - Bibeli Mimọ11 Nwọn ó ṣegbe; ṣugbọn iwọ ó wà sibẹ, gbogbo wọn ni yio si gbó bi ẹwu; Viz kapitolaYoruba Bible11 Wọn óo parẹ́ ṣugbọn ìwọ óo wà títí. Gbogbo wọn óo gbó bí aṣọ. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Wọn yóò ṣègbé, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà síbẹ̀ gbogbo wọn ni yóò di àkísà bí ẹ̀wù. Viz kapitola |