Esteri 1:2 - Bibeli Mimọ2 Li ọjọ wọnni, nigbati Ahaswerusi, ọba, joko lori itẹ ijọba rẹ̀, ti o wà ni Ṣuṣani, ãfin. Viz kapitolaYoruba Bible2 Nígbà tí ó wà lórí oyè ní Susa tíí ṣe olú-ìlú ìjọba rẹ̀, Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 Ní àkókò ìgbà náà ọba Ahaswerusi ń ṣe ìjọba ní orí ìtẹ́ ẹ rẹ̀ ní ilé ìṣọ́ ti Susa, Viz kapitola |