Esra 1:9 - Bibeli Mimọ9 Iye wọn si li eyi: ọgbọn awo-pọ̀kọ wura, ẹgbẹrun awo-pọ̀kọ fadaka, ọbẹ mọkandilọgbọn, Viz kapitolaYoruba Bible9 Iye àwọn nǹkan náà nìyí: Ẹgbẹrun kan (1,000) àwo wúrà, ẹgbẹrun kan (1,000) àwo fadaka, àwo turari mọkandinlọgbọn; Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Èyí ni iye wọn: Ọgbọ̀n àwo wúrà 30 Ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà 1,000 Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́kàn-dínlọ́gbọ̀n 29 Viz kapitola |