Eksodu 1:6 - Bibeli Mimọ6 Josefu si kú, ati gbogbo awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo iran na. Viz kapitolaYoruba Bible6 Nígbà tí ó yá, Josẹfu kú, gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ náà kú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan títí tí gbogbo ìran náà fi kú tán. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Wàyí o, Josẹfu àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú, Viz kapitola |