Eksodu 1:5 - Bibeli Mimọ5 Ati gbogbo ọkàn ti o ti inu Jakobu jade, o jẹ́ ãdọrin ọkàn: Josefu sa ti wà ni Egipti. Viz kapitolaYoruba Bible5 Gbogbo àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ ọmọ Jakọbu jẹ́ aadọrin, Josẹfu ti wà ní Ijipti ní tirẹ̀. Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 Àwọn ìran Jakọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní Ejibiti. Viz kapitola |