Online Bible

- Reklamy -




Efesu 1:16 - Bibeli Mimọ

16 Emi kò si simi lati mã dupẹ nitori nyin, ati lati mã darukọ nyin ninu adura mi;

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

16 kò sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, mo sì ń ranti yín ninu adura mi.

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 Èmi kò sì sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, àti láti máa rántí yín nínú àdúrà mi;

Viz kapitola kopírovat




Efesu 1:16

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy