Numeri 3:17 - Yoruba Bible17 Lefi ní ọmọkunrin mẹta: Geriṣoni, Kohati ati Merari, wọ́n sì jẹ́ olórí àwọn ìdílé wọn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ17 Wọnyi si ni awọn ọmọ Lefi gẹgẹ bi orukọ wọn; Gerṣoni, ati Kohati, ati Merari. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní17 Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari. Sien die hoofstuk |