Numeri 2:15 - Yoruba Bible15 Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọ́n jẹ́ ẹgbaa mejilelogun ó lé aadọta lé ní ẹgbẹjọ (45,650). Sien die hoofstukBibeli Mimọ15 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mejilelogun o le ãdọtalelẹgbẹjọ. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní15 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-méjìlélógún ó-lé-àádọ́ta-lé-ẹgbẹ̀jọ (45,650). Sien die hoofstuk |