Numeri 2:14 - Yoruba Bible14 Ẹ̀yà Gadi ni yóo pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Simeoni; Eliasafu ọmọ Reueli ni yóo jẹ́ olórí wọn. Sien die hoofstukBibeli Mimọ14 Ati ẹ̀ya Gadi: Eliasafu ọmọ Deueli ni yio si jẹ́ olori ogun ti awọn ọmọ Gadi: Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní14 Ẹ̀yà Gadi ló tẹ̀lé wọn. Olórí Gadi ni Eliasafu ọmọ Deueli. Sien die hoofstuk |