Numeri 1:54 - Yoruba Bible54 Àwọn ọmọ Israẹli sì ṣe gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún Mose. Sien die hoofstukBibeli Mimọ54 Bayi ni awọn ọmọ Israeli si ṣe; gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA ti paṣẹ fun Mose, bẹ̃ni nwọn ṣe. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní54 Àwọn ọmọ Israẹli sì ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mose. Sien die hoofstuk |